domingo, 1 de setembro de 2019

Eji ogbe


Ejí Ogbè

ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
A D’ÍFÁ FÚN OKANKAN LENIRUNWO IRÚNMOLÈ
NÌGBÁ TI WỌ́N N TỌ̀RUN BÒ WÀ SILÈ AYE

ORÍ LỌ KOKO DA Ọ̀RÚNMÌLÀ SI OKE-IGETI
ORI KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ OSUN SỌDÉ IJUMU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ DA ỌBÀTÁLÁ SỌDÉ IFỌN
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ DA ÀWỌN IYA MI-AJE SỌDÉ OTA
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ DA ṢÀNGÓ SỌDÉ KOSO
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ DA OYA SI ILÉ IRA
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ DA ÒGÚN SI IRE
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ DA ÈṢÙ SI KETU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ DA ÒRÌṢÀ-OKO SI IRAWO-AGBA
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ

ORÍ LỌ DA ẸẸGU SI ILÉ JE
ORÍ KÓÒ DÁ MI RÈ
ÒRÌṢÀ MÁ JẸẸ N SOWO AṢENU
ORÍ KÓÒ DÁ MI

MEU ORI ME ABENÇOE EM ABUNDÂNCIA
MEU ORI NÃO ME DEIXE TRABALHAR EM VÃO
💕☝👸

Nenhum comentário: